1 Kọ́ríńtì 15:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Bẹ́ẹ̀ ló ṣe rí pẹ̀lú àjíǹde àwọn òkú. A gbìn ín ní ìdíbàjẹ́; a gbé e dìde ní àìdíbàjẹ́.+ 1 Kọ́ríńtì 15:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Bí a ṣe gbé àwòrán ẹni tí a fi erùpẹ̀ dá wọ̀,+ bẹ́ẹ̀ náà ni a máa gbé àwòrán ẹni ti ọ̀run wọ̀.+