28 bákan náà ló ṣe jẹ́ pé a fi Kristi rúbọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé, kó lè ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀;+ tó bá sì fara hàn lẹ́ẹ̀kejì, kò ní jẹ́ torí ẹ̀ṣẹ̀,* àwọn tó ń fi taratara wá a fún ìgbàlà wọn sì máa rí i.+
18 Nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀, Kristi kú lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún kú mọ́ láé,+ ó jẹ́ olódodo tó kú nítorí àwọn aláìṣòdodo,+ kó lè mú yín wá sọ́dọ̀ Ọlọ́run.+ Wọ́n pa á nínú ẹran ara,+ àmọ́ a sọ ọ́ di ààyè nínú ẹ̀mí.+