Jòhánù 8:31, 32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jésù wá sọ fún àwọn Júù tó gbà á gbọ́ pé: “Tí ẹ bá dúró nínú ọ̀rọ̀ mi, ọmọ ẹ̀yìn mi ni yín lóòótọ́, 32 ẹ ó mọ òtítọ́,+ òtítọ́ á sì sọ yín di òmìnira.”+
31 Jésù wá sọ fún àwọn Júù tó gbà á gbọ́ pé: “Tí ẹ bá dúró nínú ọ̀rọ̀ mi, ọmọ ẹ̀yìn mi ni yín lóòótọ́, 32 ẹ ó mọ òtítọ́,+ òtítọ́ á sì sọ yín di òmìnira.”+