Sáàmù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ jẹ́ kí n kéde àṣẹ Jèhófà;Ó sọ fún mi pé: “Ìwọ ni ọmọ mi;+Òní ni mo di bàbá rẹ.+ Hébérù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bí àpẹẹrẹ, èwo nínú àwọn áńgẹ́lì ni Ọlọ́run sọ fún rí pé: “Ìwọ ni ọmọ mi; òní ni mo di bàbá rẹ”?+ Tó sì tún sọ fún pé: “Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi”?+
5 Bí àpẹẹrẹ, èwo nínú àwọn áńgẹ́lì ni Ọlọ́run sọ fún rí pé: “Ìwọ ni ọmọ mi; òní ni mo di bàbá rẹ”?+ Tó sì tún sọ fún pé: “Màá di bàbá rẹ̀, á sì di ọmọ mi”?+