2 Kọ́ríńtì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìpọ́njú* náà jẹ́ fún ìgbà díẹ̀, kò sì lágbára, ó ń yọrí sí ògo fún wa, ògo tí ó tóbi* gan-an, tí ó sì jẹ́ ti ayérayé;+ 1 Pétérù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa yọ̀+ torí ibi tí ẹ lè bá Kristi jìyà dé,+ kí ẹ̀yin pẹ̀lú lè yọ̀, kí ayọ̀ yín sì kún nígbà ìfihàn ògo rẹ̀.+
17 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ìpọ́njú* náà jẹ́ fún ìgbà díẹ̀, kò sì lágbára, ó ń yọrí sí ògo fún wa, ògo tí ó tóbi* gan-an, tí ó sì jẹ́ ti ayérayé;+
13 Kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa yọ̀+ torí ibi tí ẹ lè bá Kristi jìyà dé,+ kí ẹ̀yin pẹ̀lú lè yọ̀, kí ayọ̀ yín sì kún nígbà ìfihàn ògo rẹ̀.+