Jòhánù 8:31, 32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jésù wá sọ fún àwọn Júù tó gbà á gbọ́ pé: “Tí ẹ bá dúró nínú ọ̀rọ̀ mi, ọmọ ẹ̀yìn mi ni yín lóòótọ́, 32 ẹ ó mọ òtítọ́,+ òtítọ́ á sì sọ yín di òmìnira.”+ 1 Kọ́ríńtì 15:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí bí gbogbo èèyàn ṣe ń kú nínú Ádámù,+ bẹ́ẹ̀ ni a ó sọ gbogbo èèyàn di ààyè nínú Kristi.+
31 Jésù wá sọ fún àwọn Júù tó gbà á gbọ́ pé: “Tí ẹ bá dúró nínú ọ̀rọ̀ mi, ọmọ ẹ̀yìn mi ni yín lóòótọ́, 32 ẹ ó mọ òtítọ́,+ òtítọ́ á sì sọ yín di òmìnira.”+