ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Éfésù 1:9-11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 bó ṣe jẹ́ ká mọ àṣírí mímọ́+ nípa ìfẹ́ rẹ̀. Èyí bá ohun tó ń wù ú mu, ó sì tipa bẹ́ẹ̀ ṣètò 10 iṣẹ́ àbójútó kan* láti kó ohun gbogbo jọ nínú Kristi nígbà tí àwọn àkókò tí a yàn bá tó, àwọn ohun tó wà ní ọ̀run àti àwọn ohun tó wà ní ayé.+ Bẹ́ẹ̀ ni, nínú ẹni 11 tí a wà níṣọ̀kan pẹ̀lú rẹ̀, tí a sì yàn wá láti jẹ́ ajogún pẹ̀lú rẹ̀,+ ní ti pé a ti yàn wá ṣáájú nítorí ohun tí ẹni tó ń ṣe ohun gbogbo fẹ́, bí ó ṣe ń pinnu ohun tó bá ìfẹ́ rẹ̀ mu,

  • 2 Tímótì 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ó gbà wá, ó sì fi ìpè mímọ́ pè wá,+ kì í ṣe torí àwọn iṣẹ́ wa, àmọ́ torí ohun tó fẹ́ ṣe àti inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀.+ Ọjọ́ pẹ́ tí a ti fún wa ní èyí nípasẹ̀ Kristi Jésù,

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́