Ìṣe 13:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ọlọ́run ti mú un ṣẹ pátápátá fún àwa ọmọ wọn bó ṣe jí Jésù dìde;+ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà lákọsílẹ̀ nínú sáàmù kejì pé: ‘Ìwọ ni ọmọ mi, òní ni mo di bàbá rẹ.’+
33 Ọlọ́run ti mú un ṣẹ pátápátá fún àwa ọmọ wọn bó ṣe jí Jésù dìde;+ gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà lákọsílẹ̀ nínú sáàmù kejì pé: ‘Ìwọ ni ọmọ mi, òní ni mo di bàbá rẹ.’+