10 “Iye àwọn èèyàn* Ísírẹ́lì máa dà bí iyanrìn òkun tí a kò lè díwọ̀n tàbí tí a kò lè kà.+ Níbi tí a ti sọ fún wọn pé, ‘Ẹ kì í ṣe èèyàn mi,’+ a ó pè wọ́n ní, ‘Àwọn ọmọ Ọlọ́run alààyè.’+
4 Síbẹ̀, èsì wo ni ó gbọ́ láti ọ̀run? “Mo ti ṣẹ́ ẹgbẹ̀rún méje (7,000) ọkùnrin kù fún ara mi, àwọn ọkùnrin tí kò kúnlẹ̀ fún Báálì.”+5 Lọ́nà kan náà, ní àkókò yìí, àṣẹ́kù kan wà+ tí a yàn nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí.