-
Róòmù 1:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Nítorí ìhìn rere kò tì mí lójú;+ ní tòótọ́, ó jẹ́ agbára Ọlọ́run tó ń mú kí gbogbo ẹni tó ní ìgbàgbọ́ rí ìgbàlà,+ àwọn Júù lákọ̀ọ́kọ́,+ lẹ́yìn náà àwọn Gíríìkì.+ 17 Nítorí inú rẹ̀ ni a ti ń fi òdodo Ọlọ́run hàn nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ àti fún ìgbàgbọ́,+ gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè.”+
-