Diutarónómì 32:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi. Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú. Róòmù 10:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ mo béèrè pé, Ṣé Ísírẹ́lì ò mọ̀ ni?+ Wọ́n kúkú mọ̀. Lákọ̀ọ́kọ́, Mósè sọ pé: “Màá fi àwọn tí kì í ṣe orílẹ̀-èdè mú kí ẹ jowú; màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀ mú kí ẹ gbaná jẹ.”+
21 Wọ́n ti fi ohun tí kì í ṣe ọlọ́run+ mú mi bínú;*Wọ́n ti fi àwọn òrìṣà+ wọn tí kò ní láárí múnú bí mi. Torí náà, màá fi àwọn tí kì í ṣe èèyàn+ mú kí wọ́n jowú;Màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀+ mú wọn bínú.
19 Àmọ́ mo béèrè pé, Ṣé Ísírẹ́lì ò mọ̀ ni?+ Wọ́n kúkú mọ̀. Lákọ̀ọ́kọ́, Mósè sọ pé: “Màá fi àwọn tí kì í ṣe orílẹ̀-èdè mú kí ẹ jowú; màá fi orílẹ̀-èdè òmùgọ̀ mú kí ẹ gbaná jẹ.”+