2 Tímótì 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí Ọlọ́run kò fún wa ní ẹ̀mí ojo,+ àmọ́ ó fún wa ní ẹ̀mí agbára+ àti ti ìfẹ́ àti ti àròjinlẹ̀.