-
Lúùkù 22:24-26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Àmọ́, wọ́n tún bẹ̀rẹ̀ sí í bára wọn jiyàn gidigidi nípa ẹni tí wọ́n kà sí ẹni tó tóbi jù nínú wọn.+ 25 Ṣùgbọ́n ó sọ fún wọn pé: “Àwọn ọba àwọn orílẹ̀-èdè máa ń jẹ ọ̀gá lé àwọn èèyàn lórí, wọ́n sì máa ń pe àwọn tó ní àṣẹ lórí wọn ní Olóore.+ 26 Àmọ́ kò yẹ kí ẹ̀yin ṣe bẹ́ẹ̀.+ Kí ẹni tó tóbi jù láàárín yín dà bí ẹni tó kéré jù,+ kí ẹni tó jẹ́ aṣáájú sì dà bí ẹni tó ń ṣe ìránṣẹ́.
-