Mátíù 22:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n sọ pé: “Ti Késárì ni.” Ó wá sọ fún wọn pé: “Torí náà, ẹ san àwọn ohun ti Késárì pa dà fún Késárì, àmọ́ ẹ fi àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”+ Máàkù 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jésù wá sọ fún wọn pé: “Ẹ san àwọn ohun ti Késárì pa dà fún Késárì,+ àmọ́ ẹ fi àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”+ Ẹnu sì yà wọ́n sí i. Lúùkù 20:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ó sọ fún wọn pé: “Torí náà, ẹ rí i dájú pé ẹ san àwọn ohun ti Késárì pa dà fún Késárì,+ àmọ́ ẹ fi àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”+
21 Wọ́n sọ pé: “Ti Késárì ni.” Ó wá sọ fún wọn pé: “Torí náà, ẹ san àwọn ohun ti Késárì pa dà fún Késárì, àmọ́ ẹ fi àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”+
17 Jésù wá sọ fún wọn pé: “Ẹ san àwọn ohun ti Késárì pa dà fún Késárì,+ àmọ́ ẹ fi àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”+ Ẹnu sì yà wọ́n sí i.
25 Ó sọ fún wọn pé: “Torí náà, ẹ rí i dájú pé ẹ san àwọn ohun ti Késárì pa dà fún Késárì,+ àmọ́ ẹ fi àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”+