1 Kọ́ríńtì 14:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bó ṣe rí fún ẹ̀yin náà nìyẹn, torí pé ẹ̀ ń fẹ́ ẹ̀bùn ẹ̀mí lójú méjèèjì, ẹ máa wá ọ̀nà láti ní ẹ̀bùn púpọ̀ tó máa gbé ìjọ ró.+ Hébérù 10:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ẹ sì jẹ́ ká gba ti ara wa rò* ká lè máa fún ara wa níṣìírí* láti ní ìfẹ́ àti láti ṣe àwọn iṣẹ́ rere,+
12 Bó ṣe rí fún ẹ̀yin náà nìyẹn, torí pé ẹ̀ ń fẹ́ ẹ̀bùn ẹ̀mí lójú méjèèjì, ẹ máa wá ọ̀nà láti ní ẹ̀bùn púpọ̀ tó máa gbé ìjọ ró.+
24 Ẹ sì jẹ́ ká gba ti ara wa rò* ká lè máa fún ara wa níṣìírí* láti ní ìfẹ́ àti láti ṣe àwọn iṣẹ́ rere,+