Ìṣe 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ni gbogbo wọn bá dákẹ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í fetí sílẹ̀ bí Bánábà àti Pọ́ọ̀lù ṣe ń ròyìn ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* tí Ọlọ́run ti ṣe nípasẹ̀ wọn láàárín àwọn orílẹ̀-èdè. 2 Kọ́ríńtì 12:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní tòótọ́, ẹ ti rí àwọn àmì tó fi hàn pé mo jẹ́ àpọ́sítélì nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà,+ nínú àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* àti àwọn iṣẹ́ agbára.+
12 Ni gbogbo wọn bá dákẹ́, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í fetí sílẹ̀ bí Bánábà àti Pọ́ọ̀lù ṣe ń ròyìn ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* tí Ọlọ́run ti ṣe nípasẹ̀ wọn láàárín àwọn orílẹ̀-èdè.
12 Ní tòótọ́, ẹ ti rí àwọn àmì tó fi hàn pé mo jẹ́ àpọ́sítélì nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà,+ nínú àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* àti àwọn iṣẹ́ agbára.+