2 Tẹsalóníkà 3:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Lákòótán, ẹ̀yin ará, ẹ máa gbàdúrà fún wa,+ kí ọ̀rọ̀ Jèhófà* lè máa gbilẹ̀ kíákíá,+ kí a sì máa ṣe é lógo, bó ṣe rí lọ́dọ̀ yín, 2 kí a lè gbà wá lọ́wọ́ àwọn ẹni ibi àti èèyàn burúkú,+ nítorí ìgbàgbọ́ kì í ṣe ohun ìní gbogbo èèyàn.+
3 Lákòótán, ẹ̀yin ará, ẹ máa gbàdúrà fún wa,+ kí ọ̀rọ̀ Jèhófà* lè máa gbilẹ̀ kíákíá,+ kí a sì máa ṣe é lógo, bó ṣe rí lọ́dọ̀ yín, 2 kí a lè gbà wá lọ́wọ́ àwọn ẹni ibi àti èèyàn burúkú,+ nítorí ìgbàgbọ́ kì í ṣe ohun ìní gbogbo èèyàn.+