Diutarónómì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Orílẹ̀-èdè ńlá wo ló sì ní àwọn ìlànà òdodo àti àwọn ìdájọ́ bíi ti gbogbo Òfin yìí tí mò ń fi sí iwájú yín lónìí?+ Sáàmù 147:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ fún Jékọ́bù,Ó sọ àwọn ìlànà rẹ̀ àti àwọn ìdájọ́ rẹ̀ fún Ísírẹ́lì.+ 20 Kò ṣe bẹ́ẹ̀ fún orílẹ̀-èdè míì;+Wọn ò mọ nǹkan kan nípa ìdájọ́ rẹ̀. Ẹ yin Jáà!*+ Ìṣe 7:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ẹni yìí wà lára ìjọ tó wà ní aginjù, ó wà pẹ̀lú áńgẹ́lì+ tó bá a sọ̀rọ̀+ lórí Òkè Sínáì pẹ̀lú àwọn baba ńlá wa, ó sì gba àwọn ọ̀rọ̀ ìkéde mímọ́ tó jẹ́ ààyè láti fún wa.+
8 Orílẹ̀-èdè ńlá wo ló sì ní àwọn ìlànà òdodo àti àwọn ìdájọ́ bíi ti gbogbo Òfin yìí tí mò ń fi sí iwájú yín lónìí?+
19 Ó sọ ọ̀rọ̀ rẹ̀ fún Jékọ́bù,Ó sọ àwọn ìlànà rẹ̀ àti àwọn ìdájọ́ rẹ̀ fún Ísírẹ́lì.+ 20 Kò ṣe bẹ́ẹ̀ fún orílẹ̀-èdè míì;+Wọn ò mọ nǹkan kan nípa ìdájọ́ rẹ̀. Ẹ yin Jáà!*+
38 Ẹni yìí wà lára ìjọ tó wà ní aginjù, ó wà pẹ̀lú áńgẹ́lì+ tó bá a sọ̀rọ̀+ lórí Òkè Sínáì pẹ̀lú àwọn baba ńlá wa, ó sì gba àwọn ọ̀rọ̀ ìkéde mímọ́ tó jẹ́ ààyè láti fún wa.+