Sáàmù 51:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìwọ gan-an* ni mo dẹ́ṣẹ̀ sí,+Mo ti ṣe ohun tó burú ní ojú rẹ.+ Torí náà, olódodo ni ọ́ nígbà tí o bá ń sọ̀rọ̀,Ìdájọ́ rẹ sì tọ́.+
4 Ìwọ gan-an* ni mo dẹ́ṣẹ̀ sí,+Mo ti ṣe ohun tó burú ní ojú rẹ.+ Torí náà, olódodo ni ọ́ nígbà tí o bá ń sọ̀rọ̀,Ìdájọ́ rẹ sì tọ́.+