Ìṣe 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ní báyìí, kí lò ń dúró dè? Dìde, kí o ṣèrìbọmi, kí o sì wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ+ nù nípa kíké pe orúkọ rẹ̀.’+ Hébérù 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 ẹ jẹ́ ká fi ọkàn tòótọ́ àti ìgbàgbọ́ tó kún rẹ́rẹ́ wá, nígbà tí a ti wẹ ọkàn wa mọ́ kúrò nínú ẹ̀rí ọkàn burúkú,+ tí a sì ti fi omi tó mọ́ wẹ ara wa.+
16 Ní báyìí, kí lò ń dúró dè? Dìde, kí o ṣèrìbọmi, kí o sì wẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ+ nù nípa kíké pe orúkọ rẹ̀.’+
22 ẹ jẹ́ ká fi ọkàn tòótọ́ àti ìgbàgbọ́ tó kún rẹ́rẹ́ wá, nígbà tí a ti wẹ ọkàn wa mọ́ kúrò nínú ẹ̀rí ọkàn burúkú,+ tí a sì ti fi omi tó mọ́ wẹ ara wa.+