Ìṣe 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àmọ́ Ọlọ́run jí i dìde,+ bó ṣe gbà á sílẹ̀ lọ́wọ́ oró* ikú, torí ikú ò lè dì í mú títí lọ.+