1 Pétérù 3:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Bákan náà, kí ẹ̀yin aya máa tẹrí ba fún àwọn ọkọ yín,+ kó lè jẹ́ pé, tí a bá rí ẹnikẹ́ni tí kò ṣègbọràn sí ọ̀rọ̀ náà, a máa lè jèrè wọn nípasẹ̀ ìwà àwọn aya wọn+ láìsọ ohunkóhun, 2 torí pé wọ́n fojú rí ìwà mímọ́ yín+ pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀.
3 Bákan náà, kí ẹ̀yin aya máa tẹrí ba fún àwọn ọkọ yín,+ kó lè jẹ́ pé, tí a bá rí ẹnikẹ́ni tí kò ṣègbọràn sí ọ̀rọ̀ náà, a máa lè jèrè wọn nípasẹ̀ ìwà àwọn aya wọn+ láìsọ ohunkóhun, 2 torí pé wọ́n fojú rí ìwà mímọ́ yín+ pẹ̀lú ọ̀wọ̀ tó jinlẹ̀.