1 Kọ́ríńtì 7:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Síbẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Jèhófà* ṣe fún kálukú ní ìpín tirẹ̀, kí kálukú máa rìn bí Ọlọ́run ṣe pè é.+ Torí náà, mo fi àṣẹ yìí lélẹ̀ nínú gbogbo ìjọ.
17 Síbẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Jèhófà* ṣe fún kálukú ní ìpín tirẹ̀, kí kálukú máa rìn bí Ọlọ́run ṣe pè é.+ Torí náà, mo fi àṣẹ yìí lélẹ̀ nínú gbogbo ìjọ.