Ìṣe 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 àmọ́ kí a kọ̀wé sí wọn láti ta kété sí àwọn ohun tí àwọn òrìṣà ti sọ di ẹlẹ́gbin,+ sí ìṣekúṣe,*+ sí ohun tí wọ́n fún lọ́rùn pa* àti sí ẹ̀jẹ̀.+ Ìṣe 15:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 láti máa ta kété sí àwọn ohun tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà,+ láti máa ta kété sí ẹ̀jẹ̀,+ sí ohun tí wọ́n fún lọ́rùn pa*+ àti sí ìṣekúṣe.*+ Tí ẹ bá ń yẹra fún àwọn nǹkan yìí délẹ̀délẹ̀, ẹ ó láásìkí. Kí ara yín ó le o!”*
20 àmọ́ kí a kọ̀wé sí wọn láti ta kété sí àwọn ohun tí àwọn òrìṣà ti sọ di ẹlẹ́gbin,+ sí ìṣekúṣe,*+ sí ohun tí wọ́n fún lọ́rùn pa* àti sí ẹ̀jẹ̀.+
29 láti máa ta kété sí àwọn ohun tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà,+ láti máa ta kété sí ẹ̀jẹ̀,+ sí ohun tí wọ́n fún lọ́rùn pa*+ àti sí ìṣekúṣe.*+ Tí ẹ bá ń yẹra fún àwọn nǹkan yìí délẹ̀délẹ̀, ẹ ó láásìkí. Kí ara yín ó le o!”*