2 Tímótì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kódà nínú àwọn eré ìdíje, wọn kì í dé ẹni tó bá kópa ládé, àfi tó bá tẹ̀ lé àwọn òfin ìdíje náà.+