Júùdù 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní ti àwọn áńgẹ́lì tó fi ipò wọn àti ibi tó yẹ kí wọ́n máa gbé sílẹ̀,+ ó ti dè wọ́n títí láé sínú òkùnkùn biribiri, ó sì fi wọ́n pa mọ́ de ìdájọ́ ní ọjọ́ ńlá náà.+
6 Ní ti àwọn áńgẹ́lì tó fi ipò wọn àti ibi tó yẹ kí wọ́n máa gbé sílẹ̀,+ ó ti dè wọ́n títí láé sínú òkùnkùn biribiri, ó sì fi wọ́n pa mọ́ de ìdájọ́ ní ọjọ́ ńlá náà.+