32 Ẹ máa ṣọ́ra kí ẹ má bàa di ohun ìkọ̀sẹ̀ fún àwọn Júù àti àwọn Gíríìkì àti fún ìjọ Ọlọ́run,+33 bí mo ṣe ń gbìyànjú láti wu gbogbo èèyàn nínú ohun gbogbo, láìmáa wá ire ti ara mi+ bí kò ṣe ti ọ̀pọ̀ èèyàn, kí wọ́n lè rí ìgbàlà.+
4 Ìfẹ́+ máa ń ní sùúrù*+ àti inú rere.+ Ìfẹ́ kì í jowú,+ kì í fọ́nnu, kì í gbéra ga,+5 kì í hùwà tí kò bójú mu,*+ kì í wá ire tirẹ̀ nìkan,+ kì í tètè bínú.+ Kì í di èèyàn sínú.*+