ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 115:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Wọ́n ní ẹnu, àmọ́ wọn ò lè sọ̀rọ̀;+

      Wọ́n ní ojú, àmọ́ wọn ò lè ríran;

  • Hábákúkù 2:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Kí ni àǹfààní ère,

      Nígbà tó jẹ́ pé èèyàn ló gbẹ́ ẹ?

      Kí ni àǹfààní ère onírin* àti olùkọ́ èké,

      Tí ẹni tó ṣe é bá tiẹ̀ gbẹ́kẹ̀ lé e,

      Tó ṣe àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí, tí kò lè sọ̀rọ̀?+

  • 1 Kọ́ríńtì 8:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+

  • Gálátíà 4:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Síbẹ̀, nígbà tí ẹ kò mọ Ọlọ́run, ẹ̀ ń ṣẹrú àwọn tí kì í ṣe ọlọ́run.

  • 1 Tẹsalóníkà 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Nítorí àwọn fúnra wọn ń ròyìn nípa bí a ṣe kọ́kọ́ dé ọ̀dọ̀ yín àti bí ẹ ṣe fi àwọn òrìṣà yín sílẹ̀,+ tí ẹ sì yíjú sọ́dọ̀ Ọlọ́run kí ẹ lè jẹ́ ẹrú Ọlọ́run tòótọ́ àti alààyè,

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́