Hébérù 13:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ máa rántí àwọn tó wà nínú ẹ̀wọ̀n,*+ bí ẹni pé ẹ jọ wà lẹ́wọ̀n+ àti àwọn tí wọ́n ń fìyà jẹ, torí pé ẹ̀yin fúnra yín náà wà nínú ara.*
3 Ẹ máa rántí àwọn tó wà nínú ẹ̀wọ̀n,*+ bí ẹni pé ẹ jọ wà lẹ́wọ̀n+ àti àwọn tí wọ́n ń fìyà jẹ, torí pé ẹ̀yin fúnra yín náà wà nínú ara.*