-
Ìṣe 13:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ní Áńtíókù, àwọn wòlíì àti àwọn olùkọ́ wà nínú ìjọ tó wà níbẹ̀,+ àwọn ni: Bánábà, Símíónì tí wọ́n ń pè ní Nígérì, Lúkíọ́sì ará Kírénè àti Mánáénì tó kẹ́kọ̀ọ́ lọ́dọ̀ Hẹ́rọ́dù alákòóso agbègbè náà, àti Sọ́ọ̀lù.
-