24 bí a ṣe pè wọ́n ní olódodo dà bí ẹ̀bùn ọ̀fẹ́+ tí wọ́n rí gbà nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀,+ èyí tó wá nípasẹ̀ ìtúsílẹ̀ tí ìràpadà tí Kristi Jésù san mú kó ṣeé ṣe.+
13 Ó gbà wá lọ́wọ́ àṣẹ òkùnkùn,+ ó sì mú wa lọ sínú ìjọba Ọmọ rẹ̀ ọ̀wọ́n, 14 ẹni tí a tipasẹ̀ rẹ̀ gba ìtúsílẹ̀ nípa ìràpadà, ìyẹn ìdáríjì àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+