1 Kọ́ríńtì 13:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Tí mo bá sì ní ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀, tí mo lóye gbogbo àṣírí mímọ́ àti gbogbo ìmọ̀,+ tí mo ní gbogbo ìgbàgbọ́ láti ṣí àwọn òkè nípò pa dà,* àmọ́ tí mi ò ní ìfẹ́, mi ò já mọ́ nǹkan kan.*+
2 Tí mo bá sì ní ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀, tí mo lóye gbogbo àṣírí mímọ́ àti gbogbo ìmọ̀,+ tí mo ní gbogbo ìgbàgbọ́ láti ṣí àwọn òkè nípò pa dà,* àmọ́ tí mi ò ní ìfẹ́, mi ò já mọ́ nǹkan kan.*+