Kólósè 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbà tí a bá fi Kristi, ìyè wa,+ hàn kedere, nígbà náà, a ó fi ẹ̀yin náà hàn kedere pẹ̀lú rẹ̀ nínú ògo.+
4 Nígbà tí a bá fi Kristi, ìyè wa,+ hàn kedere, nígbà náà, a ó fi ẹ̀yin náà hàn kedere pẹ̀lú rẹ̀ nínú ògo.+