Róòmù 16:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ bá mi kí Pírísíkà àti Ákúílà,+ àwọn tí a jọ ń ṣiṣẹ́ Kristi Jésù, Róòmù 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bákan náà, ẹ kí ìjọ tó wà ní ilé wọn.+ Ẹ kí Épénétù àyànfẹ́ mi, tó jẹ́ àkọ́so ní Éṣíà fún Kristi. Fílémónì 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 àti sí Áfíà arábìnrin wa àti Ákípọ́sì+ tí a jọ jẹ́ ọmọ ogun àti sí ìjọ tó wà ní ilé rẹ:+