Fílípì 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Mo mọ bí èèyàn ṣe ń gbé nínú àìní,*+ mo sì mọ bí èèyàn ṣe ń gbé nínú ọ̀pọ̀. Nínú ohun gbogbo àti ní ipòkípò, mo ti kọ́ àṣírí bí a ṣe ń jẹ àjẹyó àti bí a ṣe ń wà nínú ebi, bí a ṣe ń ní púpọ̀ àti bí a ṣe ń jẹ́ aláìní.
12 Mo mọ bí èèyàn ṣe ń gbé nínú àìní,*+ mo sì mọ bí èèyàn ṣe ń gbé nínú ọ̀pọ̀. Nínú ohun gbogbo àti ní ipòkípò, mo ti kọ́ àṣírí bí a ṣe ń jẹ àjẹyó àti bí a ṣe ń wà nínú ebi, bí a ṣe ń ní púpọ̀ àti bí a ṣe ń jẹ́ aláìní.