Gálátíà 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 ẹ̀yin ọmọ mi kéékèèké,+ tí mo tún tìtorí yín wà nínú ìrora ìbímọ títí ẹ ó fi lè gbé Kristi yọ* nínú yín. 1 Tẹsalóníkà 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ mọ̀ dáadáa pé ṣe là ń gbà yín níyànjú, tí à ń tù yín nínú, tí a sì ń jẹ́rìí fún ẹnì kọ̀ọ̀kan yín,+ bí bàbá+ ṣe máa ń ṣe fún àwọn ọmọ rẹ̀,
19 ẹ̀yin ọmọ mi kéékèèké,+ tí mo tún tìtorí yín wà nínú ìrora ìbímọ títí ẹ ó fi lè gbé Kristi yọ* nínú yín.
11 Ẹ mọ̀ dáadáa pé ṣe là ń gbà yín níyànjú, tí à ń tù yín nínú, tí a sì ń jẹ́rìí fún ẹnì kọ̀ọ̀kan yín,+ bí bàbá+ ṣe máa ń ṣe fún àwọn ọmọ rẹ̀,