7 Kò sí ìkankan nínú wa, ní ti gidi, tó wà láàyè nítorí ara rẹ̀,+ kò sì sí ẹni tó kú nítorí ara rẹ̀. 8 Nítorí pé tí a bá wà láàyè, a wà láàyè fún Jèhófà,*+ tí a bá sì kú, a kú fún Jèhófà.* Torí náà, tí a bá wà láàyè tàbí tí a bá kú, a jẹ́ ti Jèhófà.*+