2 Kọ́ríńtì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí àwọn ohun ìjà wa kì í ṣe ti ara,+ àmọ́ Ọlọ́run ti mú kí wọ́n lágbára+ láti borí àwọn nǹkan tó ti fìdí múlẹ̀ gbọn-in gbọn-in. Éfésù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra ogun+ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ lè dúró gbọn-in láti dojú kọ àwọn àrékérekè* Èṣù;
4 Nítorí àwọn ohun ìjà wa kì í ṣe ti ara,+ àmọ́ Ọlọ́run ti mú kí wọ́n lágbára+ láti borí àwọn nǹkan tó ti fìdí múlẹ̀ gbọn-in gbọn-in.
11 Ẹ gbé gbogbo ìhámọ́ra ogun+ láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọ̀, kí ẹ lè dúró gbọn-in láti dojú kọ àwọn àrékérekè* Èṣù;