-
Máàkù 12:43, 44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Torí náà, ó pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sọ́dọ̀, ó sì sọ fún wọn pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín pé ohun tí opó aláìní yìí fi sílẹ̀ ju ti gbogbo àwọn yòókù tó fi owó sínú àwọn àpótí ìṣúra.+ 44 Torí gbogbo wọn fi síbẹ̀ látinú àjẹṣẹ́kù wọn, àmọ́ òun, láìka pé kò ní lọ́wọ́,* ó fi gbogbo ohun tó ní síbẹ̀, gbogbo ohun tó ní láti gbé ẹ̀mí rẹ̀ ró.”+
-