-
Ẹ́kísódù 16:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nígbà tí wọ́n fi òṣùwọ̀n ómérì wọ̀n ọ́n, kò ṣẹ́ kù lọ́wọ́ ẹni tó kó púpọ̀, kò sì ṣaláìtó fún ẹni tó kó díẹ̀.+ Ohun tí kálukú wọn máa lè jẹ ni wọ́n kó.
-