1 Kọ́ríńtì 11:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Kí èèyàn kọ́kọ́ dá ara rẹ̀ lójú lẹ́yìn tó bá ti yẹ ara rẹ̀ wò dáadáa,+ ẹ̀yìn ìgbà yẹn nìkan ni kó jẹ nínú búrẹ́dì náà, kó sì mu nínú ife náà. Gálátíà 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àmọ́ kí kálukú máa yẹ ohun tó ń ṣe wò,+ nígbà náà, yóò láyọ̀ nítorí ohun tí òun fúnra rẹ̀ ṣe, kì í ṣe torí pé ó fi ara rẹ̀ wé ẹlòmíì.+
28 Kí èèyàn kọ́kọ́ dá ara rẹ̀ lójú lẹ́yìn tó bá ti yẹ ara rẹ̀ wò dáadáa,+ ẹ̀yìn ìgbà yẹn nìkan ni kó jẹ nínú búrẹ́dì náà, kó sì mu nínú ife náà.
4 Àmọ́ kí kálukú máa yẹ ohun tó ń ṣe wò,+ nígbà náà, yóò láyọ̀ nítorí ohun tí òun fúnra rẹ̀ ṣe, kì í ṣe torí pé ó fi ara rẹ̀ wé ẹlòmíì.+