Róòmù 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nínú ìfẹ́ ará, ẹ ní ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ fún ara yín. Nínú bíbu ọlá fún ara yín, ẹ mú ipò iwájú.*+