Éfésù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Iṣẹ́ ọwọ́ Ọlọ́run ni wá,* ó dá wa+ ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù+ ká lè ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí Ọlọ́run ti ṣètò sílẹ̀ fún wa láti máa ṣe.
10 Iṣẹ́ ọwọ́ Ọlọ́run ni wá,* ó dá wa+ ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù+ ká lè ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí Ọlọ́run ti ṣètò sílẹ̀ fún wa láti máa ṣe.