Róòmù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ máa jọba lọ nínú ara kíkú yín,+ tí ẹ ó fi máa ṣe ìfẹ́ ti ara. 1 Pétérù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, mò ń gbà yín níyànjú, ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ àjèjì àti olùgbé fún ìgbà díẹ̀*+ pé kí ẹ máa sá fún ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara+ tó ń bá yín* jà.+
11 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, mò ń gbà yín níyànjú, ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ àjèjì àti olùgbé fún ìgbà díẹ̀*+ pé kí ẹ máa sá fún ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara+ tó ń bá yín* jà.+