2 Kọ́ríńtì 5:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí náà, tí ẹnikẹ́ni bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi, ó ti di ẹ̀dá tuntun; àwọn ohun àtijọ́ ti kọjá lọ;+ wò ó! àwọn ohun tuntun ti dé. Éfésù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Iṣẹ́ ọwọ́ Ọlọ́run ni wá,* ó dá wa+ ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù+ ká lè ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí Ọlọ́run ti ṣètò sílẹ̀ fún wa láti máa ṣe.
17 Nítorí náà, tí ẹnikẹ́ni bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi, ó ti di ẹ̀dá tuntun; àwọn ohun àtijọ́ ti kọjá lọ;+ wò ó! àwọn ohun tuntun ti dé.
10 Iṣẹ́ ọwọ́ Ọlọ́run ni wá,* ó dá wa+ ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù+ ká lè ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí Ọlọ́run ti ṣètò sílẹ̀ fún wa láti máa ṣe.