14 Àmọ́ nígbà tí mo rí i pé wọn kò rìn lọ́nà tó bá òtítọ́ ìhìn rere mu,+ mo sọ fún Kéfà níṣojú gbogbo wọn pé: “Bí ìwọ tí o jẹ́ Júù, bá ń gbé ìgbé ayé àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè, tí o kò ṣe bíi ti àwọn Júù, kí ló wá dé tí o fi ń sọ ọ́ di dandan pé kí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè máa tẹ̀ lé àṣà àwọn Júù?”+