Róòmù 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí inú rẹ̀ ni a ti ń fi òdodo Ọlọ́run hàn nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ àti fún ìgbàgbọ́,+ gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè.”+ Jémíìsì 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+
17 Nítorí inú rẹ̀ ni a ti ń fi òdodo Ọlọ́run hàn nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ àti fún ìgbàgbọ́,+ gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Àmọ́ ìgbàgbọ́ yóò mú kí olódodo wà láàyè.”+
23 a sì mú ìwé mímọ́ náà ṣẹ tó sọ pé: “Ábúráhámù ní ìgbàgbọ́ nínú Jèhófà,* a sì kà á sí òdodo fún un,”+ a sì wá ń pè é ní ọ̀rẹ́ Jèhófà.*+