-
Róòmù 4:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ó gba àmì kan,+ ìyẹn, ìdádọ̀dọ́,* gẹ́gẹ́ bí èdìdì* òdodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ tó ní nígbà tó ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́,* kí ó lè jẹ́ baba gbogbo àwọn tó ní ìgbàgbọ́+ nígbà tí wọ́n ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́, kí a lè kà wọ́n sí olódodo; 12 kí ó sì tún lè jẹ́ baba àwọn ọmọ tó ti dádọ̀dọ́,* kì í ṣe ti àwọn tó rọ̀ mọ́ ìdádọ̀dọ́* nìkan, àmọ́ ó tún jẹ́ baba àwọn tó ń rìn létòlétò nínú ìgbàgbọ́ tí baba wa Ábúráhámù+ ní nígbà tó ṣì jẹ́ aláìdádọ̀dọ́.*
-