Kólósè 2:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 kò sì di orí náà mú ṣinṣin,+ ipasẹ̀ ẹni tí gbogbo ara fi ń rí ohun tó nílò, tó sì so gbogbo rẹ̀ pọ̀ di ọ̀kan nípasẹ̀ àwọn oríkèé àti àwọn iṣan tó de eegun pọ̀, tó ń mú kó máa dàgbà sókè bí Ọlọ́run ṣe fẹ́.+
19 kò sì di orí náà mú ṣinṣin,+ ipasẹ̀ ẹni tí gbogbo ara fi ń rí ohun tó nílò, tó sì so gbogbo rẹ̀ pọ̀ di ọ̀kan nípasẹ̀ àwọn oríkèé àti àwọn iṣan tó de eegun pọ̀, tó ń mú kó máa dàgbà sókè bí Ọlọ́run ṣe fẹ́.+