ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Kólósè 3:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ẹ̀yin aya, ẹ máa tẹrí ba fún àwọn ọkọ yín,+ bó ṣe yẹ nínú Olúwa.

  • Títù 2:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 kí wọ́n lè máa gba àwọn ọ̀dọ́bìnrin níyànjú* láti nífẹ̀ẹ́ ọkọ wọn, láti nífẹ̀ẹ́ àwọn ọmọ wọn, 5 láti jẹ́ aláròjinlẹ̀, oníwà mímọ́, ẹni tó ń ṣiṣẹ́ ilé,* ẹni rere, tó ń tẹrí ba fún ọkọ,+ kí àwọn èèyàn má bàa sọ̀rọ̀ àbùkù sí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

  • 1 Pétérù 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Bákan náà, kí ẹ̀yin aya máa tẹrí ba fún àwọn ọkọ yín,+ kó lè jẹ́ pé, tí a bá rí ẹnikẹ́ni tí kò ṣègbọràn sí ọ̀rọ̀ náà, a máa lè jèrè wọn nípasẹ̀ ìwà àwọn aya wọn+ láìsọ ohunkóhun,

Yorùbá Publications (1987-2026)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2026 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́